2 Tímótíù 4:2 BMY

2 Wàásù ọ̀rọ̀ náà, ṣe àìsinmi ní àkókò tí ó wọ̀, àti àkókò ti kò wọ̀; bániwí, ṣe ìtọ́ni, gbani níyànjú pẹ̀lú ìpamọ́ra àti ẹ̀kọ́ gbogbo.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 4

Wo 2 Tímótíù 4:2 ni o tọ