Gálátíà 1:16 BMY

16 Láti fi ọmọ rẹ̀ hàn nínú mi, kì èmi lè máa wàásù rẹ̀ láàrin àwọn aláìkọlà; èmi kò wá ìmọ̀ lọ sọ́dọ̀ ẹnikẹ́ni,

Ka pipe ipin Gálátíà 1

Wo Gálátíà 1:16 ni o tọ