Gálátíà 3:13 BMY

13 Kírísítì ti rà wá padà kúrò lọ́wọ́ ègún òfin, ẹni tí a fi ṣe ègún fún wa: nítorí tí a ti kọ ọ́ pé, “Ìfibú ni olúkúlùkù ẹni tí a fi kọ́ sórí igi.”

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:13 ni o tọ