Gálátíà 3:14 BMY

14 Kí ìbùkún Ábúráhámù ba à lè wá sórí àwọn aláìkọlà nípa Kírísítì Jésù; kí àwa ba à lè gba ìlérí Ẹ̀mí nípa ìgbàgbọ́.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:14 ni o tọ