Gálátíà 3:18 BMY

18 Nítorí bí ìjogún náà bá ṣe ti òfin kì í ṣe ti ìlérí mọ́: ṣùgbọ́n Ọlọ́run ti fi í fún Ábúráhámù nípa ìlérí.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:18 ni o tọ