Gálátíà 3:19 BMY

19 Ǹjẹ́ kí há ni òfin? A fi kún un nítorí ìrékọjá títí irú-ọmọ tí a ti ṣe ìlérí fún yóò fi dé; a sì tipaṣẹ̀ àwọn áńgẹ́lì lànà rẹ̀ láti ọwọ́ alárinà kan wá.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:19 ni o tọ