Gálátíà 3:23 BMY

23 Ṣùgbọ́n kí ìgbàgbọ́ tó dé, a ti pa wá mọ́ lábẹ́ òfin, a sì sé wa mọ́ de ìgbàgbọ́ tí a ń bọ̀ wá fi hàn.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:23 ni o tọ