Gálátíà 3:24 BMY

24 Nítorí náà òfin ti jẹ́ olùkọ́ni láti múni wá sọ́dọ̀ Kírísítì, kí a lè dá wa láre nípa ìgbàgbọ́.

Ka pipe ipin Gálátíà 3

Wo Gálátíà 3:24 ni o tọ