20 Wọ́n fún Kalebu ní Heburoni gẹ́gẹ́ bí Mose ti wí, Kalebu sì lé àwọn ọmọ Anaki mẹtẹẹta kúrò níbẹ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1
Wo Àwọn Adájọ́ 1:20 ni o tọ