Àwọn Adájọ́ 1:21 BM

21 Ṣugbọn àwọn ọmọ Bẹnjamini kò lé àwọn ará Jebusi tí wọn ń gbé Jerusalẹmu jáde; láti ìgbà náà ni àwọn ará Jebusi ti ń bá àwọn ọmọ Bẹnjamini gbé ní Jerusalẹmu títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1

Wo Àwọn Adájọ́ 1:21 ni o tọ