34 Àwọn ará Amori ń lé àwọn ọmọ Dani sẹ́yìn sí àwọn agbègbè olókè, nítorí pé wọn kò fẹ́ gba àwọn ọmọ Dani láàyè rárá láti sọ̀kalẹ̀ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1
Wo Àwọn Adájọ́ 1:34 ni o tọ