Àwọn Adájọ́ 1:35 BM

35 Àwọn ará Amori kọ̀, wọn kò jáde ní òkè Heresi, Aijaloni ati Ṣaalibimu, ṣugbọn àwọn ọmọ Josẹfu kò fi wọ́n lọ́rùn sílẹ̀ títí tí àwọn ọmọ Josẹfu fi bẹ̀rẹ̀ sí fi tipátipá kó wọn ṣiṣẹ́.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 1

Wo Àwọn Adájọ́ 1:35 ni o tọ