15 Àwọn ọmọ Israẹli bá dá OLUWA lóhùn pé, “A ti dẹ́ṣẹ̀, fi wá ṣe ohun tí ó bá wù ọ́. Jọ̀wọ́, ṣá ti gbà wá kalẹ̀ lónìí ná.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 10
Wo Àwọn Adájọ́ 10:15 ni o tọ