16 Wọ́n bá kó gbogbo àwọn àjèjì oriṣa tí ó wà lọ́wọ́ wọn dànù, wọ́n sì ń sin OLUWA. Inú bí OLUWA, nítorí ìpọ́njú àwọn ọmọ Israẹli.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 10
Wo Àwọn Adájọ́ 10:16 ni o tọ