Àwọn Adájọ́ 11:31 BM

31 nígbà tí mo bá ń pada bọ̀, lẹ́yìn tí mo bá ti ṣẹgun wọn tán, ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ́kọ́ jáde láti wá pàdé mi láti inú ilé mi, yóo jẹ́ ti ìwọ OLUWA, n óo sì fi rú ẹbọ sísun sí ọ.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:31 ni o tọ