32 Jẹfuta bá rékọjá lọ sọ́dọ̀ àwọn ará Amoni láti bá wọn jagun, OLUWA sì fún un ní ìṣẹ́gun.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11
Wo Àwọn Adájọ́ 11:32 ni o tọ