Àwọn Adájọ́ 13:14 BM

14 Kò gbọdọ̀ fẹnu kan ohunkohun tí ó bá jáde láti inú èso àjàrà, kò gbọdọ̀ mu waini tabi ọtí líle tabi kí ó jẹ ohunkohun tí ó jẹ́ aláìmọ́. Gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún un ni kí ó ṣe.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:14 ni o tọ