Àwọn Adájọ́ 13:19 BM

19 Manoa bá mú ọmọ ewúrẹ́ náà, pẹlu ẹbọ ohun jíjẹ, ó fi wọ́n rúbọ lórí òkúta kan sí OLUWA tí ń ṣe iṣẹ́ ìyanu.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:19 ni o tọ