Àwọn Adájọ́ 13:23 BM

23 Ṣugbọn iyawo rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Bí ó bá ṣe pé OLUWA fẹ́ pa wá ni, kò ní gba ẹbọ sísun ati ẹbọ ohun jíjẹ tí a rú sí i lọ́wọ́ wa, bẹ́ẹ̀ ni kò ní fi nǹkan wọnyi hàn wá, tabi kí ó sọ wọ́n fún wa.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:23 ni o tọ