8 Manoa bá gbadura sí OLUWA, ó ní, “OLUWA, jọ̀wọ́ jẹ́ kí iranṣẹ rẹ tí o rán sí wa tún pada wá, kí ó wá kọ́ wa bí a óo ṣe máa tọ́jú ọmọkunrin tí a óo bí.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13
Wo Àwọn Adájọ́ 13:8 ni o tọ