Àwọn Adájọ́ 13:9 BM

9 Ọlọrun gbọ́ adura Manoa, angẹli Ọlọrun náà tún pada tọ obinrin yìí wá níbi tí ó jókòó sí ninu oko; ṣugbọn Manoa, ọkọ rẹ̀, kò sí lọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 13

Wo Àwọn Adájọ́ 13:9 ni o tọ