Àwọn Adájọ́ 14:11 BM

11 Nígbà tí àwọn eniyan náà rí i, wọ́n mú ọgbọ̀n ninu àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ wá láti wà pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:11 ni o tọ