Àwọn Adájọ́ 14:12 BM

12 Samsoni bá sọ fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí n pa àlọ́ kan fun yín, bí ẹ bá lè túmọ̀ àlọ́ náà láàrin ọjọ́ meje tí a ó fi se àsè igbeyawo yìí, n óo fun yín ní ọgbọ̀n ẹ̀wù funfun ati ọgbọ̀n aṣọ àríyá.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:12 ni o tọ