Àwọn Adájọ́ 15:1 BM

1 Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ní àkókò ìkórè ọkà, Samsoni mú ọmọ ewúrẹ́ kan, ó lọ bẹ iyawo rẹ̀ wò. Nígbà tí ó dé ibẹ̀, ó ní, “Mo fẹ́ wọlé lọ bá iyawo mi ninu yàrá.”Ṣugbọn baba iyawo rẹ̀ kò jẹ́ kí ó wọlé lọ bá a.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 15

Wo Àwọn Adájọ́ 15:1 ni o tọ