Àwọn Adájọ́ 15:15 BM

15 Ó rí egungun páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ pa, ó mú un, ó sì fi pa ẹgbẹrun ninu àwọn ará Filistia.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 15

Wo Àwọn Adájọ́ 15:15 ni o tọ