Àwọn Adájọ́ 19:5 BM

5 Ní ọjọ́ kẹrin, wọ́n gbéra ní òwúrọ̀ kutukutu wọ́n fẹ́ máa lọ. Ṣugbọn baba ọmọbinrin náà rọ̀ ọ́ pé kí ó jẹ oúnjẹ díẹ̀ kí ó tó máa lọ, kí ó lè lágbára.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:5 ni o tọ