Àwọn Adájọ́ 19:6 BM

6 Àwọn ọkunrin mejeeji bá jókòó, wọ́n jẹ, wọ́n mu, lẹ́yìn náà ni baba ọmọbinrin yìí tún dáhùn pé, “Jọ̀wọ́ kúkú dúró ní alẹ́ yìí kí o máa gbádùn ara rẹ.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 19

Wo Àwọn Adájọ́ 19:6 ni o tọ