Àwọn Adájọ́ 2:23 BM

23 Nítorí náà, OLUWA fi àwọn orílẹ̀-èdè náà sílẹ̀ ninu ilẹ̀ náà, kò tètè lé wọn jáde bí kò ti fún Joṣua lágbára láti ṣẹgun wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 2

Wo Àwọn Adájọ́ 2:23 ni o tọ