Àwọn Adájọ́ 3:1 BM

1 OLUWA fi àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi sílẹ̀ láti fi dán Israẹli wò, pàápàá jùlọ, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọn kò tíì ní ìrírí ogun jíjà ní ilẹ̀ Kenaani.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:1 ni o tọ