Àwọn Adájọ́ 3:2 BM

2 Kí àwọn ọmọ Israẹli lè mọ̀ nípa ogun jíjà, pataki jùlọ, ìṣọ̀wọ́ àwọn tí wọn kò mọ̀ nípa ogun jíjà tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:2 ni o tọ