24 Àwọn ọmọ Israẹli bá kúrò níbẹ̀, gbogbo wọ́n sì pada sí ilẹ̀ wọn, olukuluku pada lọ sí ìlú rẹ̀, sí ààrin ẹbí rẹ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21
Wo Àwọn Adájọ́ 21:24 ni o tọ