Àwọn Adájọ́ 21:25 BM

25 Kò sí ọba ní ilẹ̀ Israẹli ní gbogbo àkókò náà, olukuluku bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣe bí ó ti tọ́ ní ojú ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 21

Wo Àwọn Adájọ́ 21:25 ni o tọ