Àwọn Adájọ́ 3:20 BM

20 Ehudu bá tọ̀ ọ́ lọ, níbi tí òun nìkan jókòó sí ninu yàrá tútù kan, lórí òrùlé ilé rẹ̀, ó wí fún un pé, “Ọlọ́run rán mi ní iṣẹ́ kan sí ọ,” ọba bá dìde níbi tí ó jókòó sí.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:20 ni o tọ