Àwọn Adájọ́ 3:7 BM

7 Àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA, wọ́n gbàgbé OLUWA Ọlọrun wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bọ oriṣa Baali ati Aṣerotu.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:7 ni o tọ