Àwọn Adájọ́ 3:8 BM

8 Nítorí náà, inú bí OLUWA sí wọn, ó sì fi wọ́n lé Kuṣani Riṣataimu ọba Mesopotamia lọ́wọ́; wọn sì sìn ín fún ọdún mẹjọ.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:8 ni o tọ