Àwọn Adájọ́ 4:16 BM

16 Baraki lépa àwọn kẹ̀kẹ́ ogun ati àwọn ọmọ ogun Sisera títí dé Haroṣeti-ha-goimu, wọ́n sì fi idà pa àwọn ọmọ ogun Sisera láìku ẹyọ ẹnìkan.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:16 ni o tọ