Àwọn Adájọ́ 4:17 BM

17 Ṣugbọn Sisera sá lọ sí àgọ́ Jaeli, aya Heberi, ará Keni, nítorí pé alaafia wà ní ààrin Jabini, ọba Hasori, ati ìdílé Heberi ará Keni.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:17 ni o tọ