Àwọn Adájọ́ 6:10 BM

10 Mo kìlọ̀ fún yín pé, èmi ni OLUWA Ọlọrun yín, ati pé ẹ kò gbọdọ̀ bọ oriṣa àwọn ará Amori tí ẹ̀ ń gbé ilẹ̀ wọn, ṣugbọn ẹ kò gbọ́ tèmi.’ ”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6

Wo Àwọn Adájọ́ 6:10 ni o tọ