9 Mo gbà yín lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti, ati gbogbo àwọn tí wọn ń ni yín lára. Mo lé wọn jáde fún yín, mo sì fi ilẹ̀ wọn fun yín.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6
Wo Àwọn Adájọ́ 6:9 ni o tọ