8 OLUWA rán wolii kan sí wọn. Wolii náà bá sọ fún wọn pé, “OLUWA, Ọlọrun Israẹli ní, ‘Mo ko yín wá láti ilẹ̀ Ijipti, mo ko yín kúrò ní oko ẹrú.
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 6
Wo Àwọn Adájọ́ 6:8 ni o tọ