Àwọn Adájọ́ 8:19 BM

19 Ó dáhùn, ó ní, “Arakunrin mi ni wọ́n, ìyá kan náà ni ó bí wa. Bí OLUWA ti wà láàyè, bí ó bá jẹ́ pé ẹ dá wọn sí ni, ǹ bá dá ẹ̀yin náà sí.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:19 ni o tọ