Àwọn Adájọ́ 8:20 BM

20 Ó bá pe Jeteri àkọ́bí rẹ̀, ó ní, “Dìde, kí o sì pa wọ́n,” ṣugbọn ọmọ náà kò fa idà rẹ̀ yọ nítorí pé ẹ̀rù ń bà á, nítorí ọmọde ni.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:20 ni o tọ