Àwọn Adájọ́ 8:6 BM

6 Àwọn ìjòyè Sukotu dá a lóhùn, wọ́n ní, “Ṣé ọwọ́ rẹ ti tẹ Seba ati Salimuna ni, tí a óo fi fún ìwọ ati àwọn ọmọ ogun rẹ ní oúnjẹ?”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:6 ni o tọ