Àwọn Adájọ́ 8:7 BM

7 Gideoni dá wọn lóhùn pé, “Kò burú, nígbà tí OLUWA bá fi Seba ati Salimuna lé mi lọ́wọ́, ẹ̀gún ọ̀gàn aṣálẹ̀ ati òṣùṣú ni n óo fi ya ẹran ara yín.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 8

Wo Àwọn Adájọ́ 8:7 ni o tọ