37 Gaali tún dáhùn, ó ní, “Tún wò ó, àwọn eniyan kan ń bọ̀ láti agbede meji ilẹ̀ náà, àwọn kan sì ń bọ̀ láti apá ibi igi Oaku àwọn tíí máa ń wo iṣẹ́.”
Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 9
Wo Àwọn Adájọ́ 9:37 ni o tọ