Ẹkún Jeremaya 1:20 BM

20 “Bojúwò mí, OLUWA,nítorí mo wà ninu ìpọ́njú,ọkàn mi ti dàrú, inú mi bàjẹ́,nítorí pé mo ti hùwà ọ̀tẹ̀ lọpọlọpọ.Níta gbangba, ogun ń pa mí lọ́mọ;bákan náà ni ikú ń bẹ ninu ilé.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:20 ni o tọ