Ẹkún Jeremaya 1:21 BM

21 “Gbọ́ bí mo ti ń kérora,kò sí ẹnìkan tí yóo tù mí ninu.Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ti gbọ́ nípa ìyọnu mi;inú wọn sì dùn,pé ìwọ ni o kó ìyọnu bá mi.Jẹ́ kí ọjọ́ tí o dá tètè pé,kí àwọn náà lè dàbí mo ti dà.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:21 ni o tọ