Ẹkún Jeremaya 2:2 BM

2 OLUWA ti pa gbogbo ibùgbé Jakọbu run láìsí àánú.Ó ti fi ibinu wó ibi ààbò Juda lulẹ̀.Ó ti rẹ ìjọba ati àwọn aláṣẹ rẹ̀ sílẹ̀,ó fi àbùkù kàn wọ́n.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:2 ni o tọ