Ẹkún Jeremaya 2:3 BM

3 Ó ti fi ibinu gbígbóná rẹ̀,pa àwọn alágbára Israẹli;ó kọ̀, kò ràn wọ́n lọ́wọ́,nígbà tí àwọn ọ̀tá dojú kọ wọ́n.Ó jó àwọn ọmọ Jakọbu bí iná,ó sì pa gbogbo ohun tí wọn ní run.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:3 ni o tọ