Ẹkún Jeremaya 2:5 BM

5 OLUWA ṣe bí ọ̀tá,ó ti pa Israẹli run.Ó ti pa gbogbo ààfin rẹ̀ run,ó sọ àwọn ibi ààbò rẹ̀ di àlàpàó sì sọ ọ̀fọ̀ ati ẹkún Juda di pupọ.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:5 ni o tọ